ÑJÉ ENÌKAN Ñ SÒRÒ NÍPA DASH NÍ ORÍLÈ ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ?

ÑJÉ ENÌKAN Ñ SÒRÒ NÍPA DASH NÍ ORÍLÈ ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ? Orúko tí à ñ jé ni Dashsquard Nigeria. Dashsquard jé ìgbìmò eléni Marun un láti orísirísi igun lórílè_èdè nàíjíríà pèlú ìlépa kan soso fún ìtéwógbà Dash ní orílè_èdè nàíjíríà. Kíwáni DASH? Dash jé owó dígítàlì tí o lèná níbikíbi. Gégé bíi ìtàkùn ayélujára Wikipedia.org ni orísun tíó sí elégbéjegbé cryptocurrency tí èròñgbàà wón jé òré olùmúlò owó dígítàlì ní gbogbo àgbáyé jùlo. ...