ÑJÉ ENÌKAN Ñ SÒRÒ NÍPA DASH NÍ ORÍLÈ ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ?

ÑJÉ ENÌKAN Ñ SÒRÒ NÍPA DASH NÍ ORÍLÈ ÈDÈ NÀÍJÍRÍÀ?                           
Orúko tí à ñ jé ni Dashsquard Nigeria.       
Dashsquard jé ìgbìmò eléni Marun un láti orísirísi igun lórílè_èdè nàíjíríà pèlú ìlépa kan
soso fún ìtéwógbà Dash ní orílè_èdè nàíjíríà. 


                                               
Kíwáni DASH?                                   
Dash jé owó dígítàlì tí o lèná níbikíbi. Gégé bíi ìtàkùn ayélujára Wikipedia.org ni orísun tíó sí
elégbéjegbé cryptocurrency tí èròñgbàà wón jé òré olùmúlò owó dígítàlì ní gbogbo àgbáyé
jùlo. 
                                                   
Nítorí náà,kíni mo ñ so? Dash jé owó sùgbón ní ìlànà dígítàlì.Bí o ti lèná naira re láti san
owó oun tí obá rà béè náà ni olè náà owó dígítàlì (DASH).   


Kín ni oun tí mòun kòwé nípa rè,Dashsqard àbi? Béèni!   

                  
Àwa ni egbé owo igbalode ti a ko le foju ri ti ko ni owo ijoba ninu àkókó ní orílè_èdè nàíjíríà
pèlú ìfé tíó nípon fun Dash.Gbogbo wa lati fi owó wa dókòwò fún Dash pátápátá béèni akòsì
bojú wèyìn tàbí kábàámò léèkan rí pé ase béè nítorí pé owó igbalode ti a kole foju ri bíi
Dash ni gbogbo ènìyàn nílò ní orílè_èdè nàíjíríà báyìí.       
                                            
Dashsquard ní èrò láti gbilè ní orílè_èdè nàíjíríà. Akitiyan wa ni kía ri dájú pé nínú eni Márùn
ún tí a bábá pàdé ní òpônà orílè_èdè nàíjíríà, méjì nínú won ti gbódò mò nípa Dash.Akòníí
wa láti aòrò nípa owó mííran àmó eyòkan yìí DASH. 
Dash yóò mú àyípadà ñlá bá bí àwon omo orílè_èdè nàíjíríà ti í rí owó.         
Aní atónà fún odún tí awà yi 2017,àtipé atise àseyorí tópò ní san an san an.     

Síse alábàápàdé àwon omo egbé Dashsquard.   
                                   
Ògúsèye Olájùwón Michael jé onísòwò lórísirísi,amojú èro komputa,agbòròso
gbogboògbò àti òùnko wanabe.Óti bèrè oníírúúrú ní owo igbalode ti a ko le foju ri tíó je mó
àyè láti odi ìgbé owó àjo ayánilówó láti se pàsípààrò àti béèbéè lo.                       
Ìfé rè tíó gbòòrò fun owo igbalode ti a ko le foju ri lómú won kópa nínú Dashsqard.Ójé òkan
àwon tíó bèrè gidicoin.com àti olùdásílè àti olùdarí fún egbé DI(Dash investment) èyí tíó ti
gbòòrò gan an lópò odún séyìn.   Chinko:Gégé bíi amojú èro jùlo tíó kópa dakuntakun nínú
Dash láti ìgbàtí ótigbó nípa owó nàá.

                                     
Pius Anyebe jé ògbólògbó òsìsé komputa.Ókàwé gboyè lórí ìmò íjìnlè èro komputa.Ótiún
kópa ribiribi nínú ìlòmípo cryptocurrency fún ju odún mérin lo báàyí.Ójé olùdásílè.Pius jé igi ogbà wa ní gbogbo àseyorí isé àkànse tí atise ní ìlú.Ójé Olùyàwòrán orí èro ayélujára,baálé
ilé pàápá jùlo ótújé bàbà rere.











                                                 
David Chinonso Mógàjí jé asíwájú àwon tóñmú ìdàgbásókè bá DI,Dashsquard àti isé
àkànse wa tí ó n lo lówó ìyen ni Dash Nigeria website. Ójé òkan nínú àwon tíó fi egbé

ìdókòwò lélè.Agbódegbà lówólówó fún crypto àti eni tógboyè nípa ìmò èro komputa.                                           
Ójé omo egbé tíó ti pé ní àwùjo nàíjíríà.Wón mòó dájú fún ìjàjàgbara fún  Dash ní ìpínlè tíó
ti dìde.Ógbajúmò nípa télígírààmù tí a pèní sofo(empty).         







Blessing Aboi ti dààmú lórí èro ayélujára fún ìgbà pípé,léyin náà nió sàwárí Dash láti orí ìtàkùn ìtàkùròso waní ìlú Kàdúná.Láti ìgbà nàá ni otinun se akitiyan láti sòrò nípa Dash fún
òpòlópò ènìyàn ní orílè_èdè nàíjíríà, Ósìtún sètò láti ní ìpàdé àti àpèjo pèlú òpò ènìyàn síi nípa Dash ní orílè_èdè nàíjíríà.           
Arábìrin nàá jé eni tóní ìmò nípa ìsirò,agbòròso gbogboògbò àti CFO fún DI àti Dashsquard.
Òun ni olùdásílè.         
Kín ni óti jé àseyórí wa séyìn?               
Atiseju ìpàdé méfà tíó jé pé àwon tíó kéré tan tíwón kópa ni ogójì ènìyàn níbi ìpàdé kòòkan.òkan nínú àwon ènìyàn wa Pius Anyebe dá olùpààrò tíó tà tíó ra Dash pèlú owó ilè wa tijé ìrànlówó ñlá fún àwon olùdókòwò wa titun.           
Adá alt coins exchanger àkókó sílè ní orílè_èdè nàíjíríà pèlú àwon ènìyàn tíó ju òòdúnrún lo tí ìdàgbàsókè sì n bá a lójojúmó.                                                   



Àwon àfojúsùn un wa                           
1. Aó ma níju ìpàdé mewa lo fún osù kokànlá odún 2017.       
                   
2. Aó ni àpèjo pàtàkì fún àwon ológun nàíjíríà tíó ju igba lo lo.Alèrí kókó ìpàdé nàá
níbí.                 
                         
3. Atún n gbòrò lórí bí aselè mo ìwúlò fún  Dash ni orílè_èdè nàíjíríà. Àñsèto láti ní ìtàkùn
ayélujára Dash ní orílè_èdè nàíjíríà. Àfojúsùn wa nìyí àti àmúye fún ààyè.   

i. egbé alájorò.                 
                    
ii. síse àfikún owó lórí èro alágbèéká láti ìtàkùn alátagbà nípa lílo
Dash.     
                                    
iii. síse àkóónú ètò ìsàkóso fún àwon dñkdwé lórí ìtàkùn alátagbà. 

iv. àjosepò àwon ilé isé lórí ayélujára(erù tí wón ti lo àti tuntun nípa lílo DASH
nìkan).   
                             
v. ìgbanisísé fún Dash Nigeria Developers(dash ni wón yóò sanwó).
vi. ìsèlè okùnfà ìpàdé/sémínà/àpèjo.

vii. àjosepò gidicoin Api fún rírà àti títà dash.   
                              
viii. Amáase àgbékalè Dash start-up kits fún àwon ìpàdé.     
                            
iv. Aówà níbi àpèjo block chain ní ìlú àbújá ní ojó karùndínlógún osùn yí.     

ix. Gúúsù Kàdúná yóò màá se àjòdún ijó ìbílè olódodún won tí àwon tóju egbèrún méta
ènìyàn tí asìti pàrowà si won láti lo Dash bí owó ìwolé won àti láti fi ra oúnje níbi àjòdún
nàá. Aó ma sètò fún àwon tóju èédégbèta ènìyàn kí ayeye nàá tó bèrè láti kówon nípa
Dash.   
             
xii. Egbé Dashsquard yóò maa se ògbufò ìròyìn nípa Dash àti àlàyé ní orísii èdè méta
gbòógi ní orílè_èdè nàíjíríà: Haúsá,Yorùbá àti Ìgbò.Aó ma te ìwé ìwéwó àti títe ìwé kíkà
fún àwon aré agbègbè láti kà.                                     
Àwon eléyìí jé díè lára àwon ìlépa wa kí odún yìí tó parí.
                                       
Adúpé Dash nation

Comments